Lines Matching refs:wo
7 …wo̩n è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn sí àti ìké̩gàn àwo̩n è̩tó̩ wò̩nyí ti s̩e okùnfà fún àwo̩n ìwà búburú kan, tó…
9 …wo̩n è̩tó o̩mo̩nìyàn lábé̩ òfin, bí a kò bá fé̩ ti àwo̩n ènìyàn láti ko̩jú ìjà sí ìjo̩ba ipá àti t…
11 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí ìdàgbàsókè ìbás̩epò̩ ti ò̩ré̩‐sí‐ò̩ré̩ wà láàrin àwo̩n orílè̩‐èdè,
13 … àgbáyé tún ti te̩nu mó̩ ìpinnu tí wó̩n ti s̩e té̩lè̩ nínú ìwé àdéhùn wo̩n, pé àwo̩n ní ìgbàgbó̩ n…
15 …wo̩n o̩mo̩ e̩gbé̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé ti jé̩jè̩é̩ láti fo̩wó̩s̩owó̩ pò̩ pè̩lú Àjo̩ náà,…
17 Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩…
21 …wo̩n yóò sì rí i pé àwo̩n lo ètò‐ìkó̩ni àti ètò‐è̩kó̩ láti s̩e ìgbéláruge̩ ìbò̩wò̩ fún è̩tó̩ àti ò…
24 …dó̩gba. Wó̩n ní è̩bùn ti làákàyè àti ti è̩rí‐o̩kàn, ó sì ye̩ kí wo̩n ó máa hùwà sí ara wo̩n gé̩gé̩…
27 …wo̩n orílè̩‐èdè tàbí nítorí ètò‐ìs̩èlú tàbí ètò‐ìdájó̩ orílè̩‐èdè rè̩; orílè̩‐èdè náà ìbáà wà ní ò…
52 …ì kún, láti s̩àlàyé ara rè̩ ní gban̄gba, níwájú ilé‐e̩jó̩ tí kò s̩ègbè, kí wo̩n lè s̩e ìpinnu lórí…
57 …s̩e àwo̩n àfojúfò kàn nígbà tó jé̩ pé lásìkò tí èyí s̩e̩lè̩, irú ìwà bé̩è̩ tàbí irú àfojúfò bé̩è̩ …
78 …wo̩n, kí wó̩n sì dá e̩bí ti wo̩n sílè̩ láìsí ìkanilápá‐kò kankan nípa è̩yà wo̩n, tàbí orílè̩‐èdè w…
80 … kò gbo̩dò̩ s̩e ìgbeyàwó kan láìjé̩ pé àwo̩n tí ó fé̩ fé̩ ara wo̩n ní òmìnira àto̩kànwá tó péye lá…
85 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti dá ohun ìní ara rè̩ ní tàbí láti ní in papò̩ pè̩lú àwo̩n mìíràn.
90 … sì fún e̩yo̩ e̩nì kan tàbí àkójo̩pò̩ ènìyàn láàyè láti s̩e è̩sìn wo̩n àti ìgbàgbó̩ wo̩n bó s̩e je…
96 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmìnira láti pé jo̩ pò̩ àti láti dara pò̩ mó̩ àwo̩n mìíràn ní àlàáf…
101 …è̩tó̩ láti kópa nínú ìs̩àkóso orílè̩‐èdè rè̩, yálà fúnra rè̩ tàbí nípasè̩ àwo̩n as̩ojú tí a kò fi …
105 3. I fé̩ àwo̩n ènìyàn ìlú ni yóò jé̩ òkúta ìpìlè̩ fún à s̩e̩ ìjo̩ba; a ó máa fi ìfé̩ yìí hàn nípasè…
108 …wo̩n è̩tó̩ tí ó bá o̩rò̩‐ajé, ìwà láwùjo̩ àti às̩à àbínibí mu; àwo̩n è̩tó̩ tí ó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí…
115 …ti gbé ayé tí ó bu iyì kún ènìyàn; a sì lè fi kún owó yìí nípasè̩ orís̩ìí àwo̩n ètò ìrànló̩wó̩ mìí…
117 …gbé̩ òs̩ìs̩é̩ sílè̩ àti láti dara pò̩ mó̩ irú e̩gbe̩; bé̩è̩ láti dáàbò bo àwo̩n ohun tí ó je̩ é̩ l…
123 …yé tó bójú mu nínú èyí tí òun àti e̩bí rè̩ yóò wà ní ìlera àti àlàáfíà, tí wo̩n yóò sì ní oúnje̩, …
125 …wo̩n abiyamo̩ àti àwo̩n o̩mo̩dé. Gbogbo àwo̩n o̩mo̩dé yóò máa je̩ àwo̩n àn fàní ààbò kan náà nínú …
128 …àwo̩n ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩. E̩kó̩ ní ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩ yìí sì gbo̩dò̩ jé̩ dandan. A gbo…
130 …wo̩n ènìyàn bò̩wò̩ fún è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn àti àwo̩n òmìnira wo̩n, tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí. E tò è̩kó̩ …
132 3. Àwo̩n òbí ló ní è̩tó̩ tó ga jù lo̩ láti yan è̩kó̩ tí wó̩n bá fé̩ fún àwo̩n o̩mo̩ wo̩n.
135 …gbo ohun àmús̩e̩ wà ibè̩, kí ó sì kópa nínú ìdàgbàsókè ìmò̩ sáyé̩n sì àti àwo̩n àn fàní tó ń ti ib…
140 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ètò nínú àwùjo̩ rè̩ àti ní gbogbo àwùjo̩ àgbáyé níbi tí àwo̩n è̩tó̩ òm…
143 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní àwo̩n ojús̩e kan sí àwùjo̩, nípasè̩ èyí tí ó fi lè s̩eé s̩e fún e̩ni náà lát…
145 …i fi ò̩wò̩ àti ìmo̩yì tí ó tó̩ fún è̩tó̩ àti òmìnira àwo̩n e̩lòmíràn nígbà tí e̩ni náà bá ń lo àwo…
147 3. A kò gbo̩dò̩ lo àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí rárá, ní ò̩nà yòówù kó jé̩, tó bá lòdì sí àwo̩n è…
150 …lè̩‐èdè kan tàbí àkójo̩pò̩ àwo̩n ènìyàn kan tàbí e̩nìké̩ni ní è̩tó̩ láti s̩e ohunkóhun tí yóò mú ì…