Lines Matching +refs:w +refs:e

5 Bí ó ti jé̩ pé s̩ís̩e àkíyèsí iyì tó jé̩ àbímó̩ fún è̩dá àti ìdó̩gba è̩tó̩ t̩í kò s̩eé mú kúrò tí è…
7wò̩nyí ti s̩e okùnfà fún àwo̩n ìwà búburú kan, tó mú è̩rí‐o̩kàn è̩dá gbo̩gbé̩, tó sì jé̩ pé ìbè̩rè…
9 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí a dáàbò bo àwo̩n è̩tó o̩mo̩nìyàn lábé̩ òfin, bí a kò bá fé̩ ti àwo̩n…
11 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí ìdàgbàsókè ìbás̩epò̩ ti ò̩ré̩‐sí‐ò̩ré̩ wà láàrin àwo̩n orílè̩‐èdè,
13wó̩n ti s̩e té̩lè̩ nínú ìwé àdéhùn wo̩n, pé àwo̩n ní ìgbàgbó̩ nínú è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn tó jé̩ kò‐s̩eé…
15e̩gbé̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé ti jé̩jè̩é̩ láti fo̩wó̩s̩owó̩ pò̩ pè̩lú Àjo̩ náà, kí won lè …
17 Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩…
21e ìkéde káríayé ti è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn, gé̩gé̩ bí ohun àfojúsùn tí gbogbo è̩dá àti orílè̩‐èdè jo̩ ń l…
24 …ó̩gba. Wó̩n ní è̩bùn ti làákàyè àti ti è̩rí‐o̩kàn, ó sì ye̩ kí wo̩n ó máa hùwà sí ara wo̩n gé̩gé̩ …
27e; ìyàtò̩ bí i ti è̩yà ènìyàn, àwò̩, ako̩‐n̄‐bábo, èdè, è̩sìn, ètò ìs̩èlú tàbí ìyàtò̩ nípa èrò e̩n…
31 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti wà láàyè, è̩tó̩ sí òmìnira àti è̩tó̩ sí ààbò ara rè̩.
34 A kò gbo̩dò̩ mú e̩niké̩ni ní e̩rú tàbí kí a mú un sìn; e̩rú níní àti ò wò e̩rú ni a gbo̩dò̩ fi òfin…
37 A kò gbo̩dò̩ dá e̩nì ké̩ni lóró tàbí kí a lò ó ní ìlò ìkà tí kò ye̩ o̩mo̩ ènìyàn tàbí ìlò tó lè tàb…
43 …ààbò tó dó̩gba kúrò ló̩wó̩ ìyàsó̩tò̩ yòówù tí ìbáà lòdì sí ìkéde yìí àti è̩tó̩ kúrò ló̩wó̩ gbogbo …
46 … sí àtúns̩e tó jo̩jú ní ilé‐e̩jó̩ fún ìwà tó lòdì sí è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn, tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí gé̩gé…
50 Abala ke̩wàá.
52 …ún, láti s̩àlàyé ara rè̩ ní gban̄gba, níwájú ilé‐e̩jó̩ tí kò s̩ègbè, kí wo̩n lè s̩e ìpinnu lórí è̩…
55wí pé ó jàrè títí è̩bi rè̩ yóò fi hàn lábé̩ òfin nípasè̩ ìdájó̩ tí a s̩e ní gban̄gba nínú èyí tí e
57e̩nìké̩ni fún pé ó hu ìwà kan tàbí pé ó s̩e àwo̩n àfojúfò kàn nígbà tó jé̩ pé lásìkò tí èyí s̩e̩lè…
60e àyo̩júràn sí ò̩rò̩ ìgbésí ayé rè̩, tàbí sí ò̩rò̩e̩bí rè̩ tàbí sí ò̩rò̩ ìdílé rè̩ tàbí ìwé tí a k…
63 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti rìn káàkiri ní òmìnira kí ó sì fi ibi tó bá wù ú s̩e ìbùgbé láàri…
65 … è̩tó̩ láti kúrò lórílè̩‐èdè yòówù kó jé̩, tó fi mó̩ orílè̩‐èdè tirè̩, kí ó sì tún padà sí orílè̩‐…
68 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti wá ààbò àti láti je̩ àn fàní ààbò yìí ní orílè̩‐èdè mìíràn nígbà …
70 …. A kò lè lo è̩tó̩ yìí fún e̩ni tí a bá pè lé̩jó̩ tó dájú nítorí e̩ s̩è̩ tí kò je̩ mó̩ ò̩rò̩ ìs̩èl…
75 …. A kò lè s̩àdédé gba è̩tó̩ jíjé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè e̩ni ló̩wó̩ e̩nìké̩ni láìnídìí tàbí kí a kò̩ fú…
78wó̩n sì dá e̩bí ti wo̩n sílè̩ láìsí ìkanilápá‐kò kankan nípa è̩yà wo̩n, tàbí orílè̩‐èdè wo̩n tàbí …
80 2. A kò gbo̩dò̩ s̩e ìgbeyàwó kan láìjé̩ pé àwo̩n tí ó fé̩ fé̩ ara wo̩n ní òmìnira àto̩kànwá tó péye…
82 3. E̩bí jé̩ ìpìlè̩ pàtàkì àdánidá ní àwùjo̩, ó sì ní è̩tó̩ pé kí àwùjo̩ àti orílè̩‐èdè ó dáàbò bò ó.
87 2. A kò lè s̩àdédé gba ohun ìní e̩nì kan ló̩wó̩ rè̩ láìnídìí.
90e̩ sìn. E̩tó̩ yìí sì gbani láàyè láti pààrò̩ e̩ sìn tàbí ìgbàgbó̩ e̩ni. Ó sì fún e̩yo̩ e̩nì kan tà…
93wù ú, kí ó sì so̩ irú ìmò̩ràn bé̩è̩ jáde; è̩tó̩yìí gbani láàyè láti ní ìmò̩ràn yòówù láìsí àtakò l…
98 2. A kò lè fi ipá mú e̩nìké̩ni dara pò̩ mó̩ e̩gbé̩ kankan.
103 2. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ tó dó̩gba láti s̩e is̩é̩ ìjo̩ba ní orílè̩‐èdè rè̩.
105 … jé̩ òkúta ìpìlè̩ fún à s̩e̩ ìjo̩ba; a ó máa fi ìfé̩ yìí hàn nípasè̩ ìbò tòótó̩ tí a ó máa dì láti…
108wùjo̩ ló ní è̩tó̩ sí ìdáàbò bò láti o̩wó̩ ìjo̩ba àti láti jé̩ àn fà ní àwo̩n è̩tó̩ tí ó bá o̩rò̩‐a…
111 …̩is̩é̩, láti yan irú is̩é̩ tí ó wù ú, lábé̩ àdéhùn tí ó tó̩ tí ó sì tún ro̩rùn, kí ó sì ní ààbò kú…
115 …tí yóò sì tó fún òun àti e̩bí rè̩ láti gbé ayé tí ó bu iyì kún ènìyàn; a sì lè fi kún owó yìí nípa…
117 4. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti dá e̩gbé̩ òs̩ìs̩é̩ sílè̩ àti láti dara pò̩ mó̩ irú e̩gbe̩; bé̩è̩ …
123e̩bí rè̩ yóò wà ní ìlera àti àlàáfíà, tí wo̩n yóò sì ní oúnje̩, as̩o̩, ilégbèé, àti àn fàní fún ìw
125 …ìtó̩jú àti ìrànló̩wó̩ pàtàkì fún àwo̩n abiyamo̩ àti àwo̩n o̩mo̩dé. Gbogbo àwo̩n o̩mo̩dé yóò máa je…
128 …èsè è̩kó̩ is̩é̩‐o̩wó̩, àti ti ìmò̩‐è̩ro̩ fún àwo̩n ènìyàn lápapò̩. Àn fàní tó dó̩gba ní ilé‐è̩kó̩ …
130wájú tó péye bá è̩dá ènìyàn, kí ó sì túbò̩ rí i pé àwo̩n ènìyàn bò̩wò̩ fún è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn àti àw…
132 3. Àwo̩n òbí ló ní è̩tó̩ tó ga jù lo̩ láti yan è̩kó̩ tí wó̩n bá fé̩ fún àwo̩n o̩mo̩ wo̩n.
135 …̩ pé a fi ipá mú un láti kópa nínú àpapò̩ ìgbé ayé àwùjo̩ rè̩, kí ó je̩ ìgbádùn gbogbo ohun àmús̩e
137 …àní ìmo̩yì àti ohun ìní tí ó je̩ yo̩ láti inú is̩é̩ yòówù tí ó bá s̩e ìbáà s̩e ìmò̩ sáyé̩n sì, ìwé…
140 …̩tó̩ sí ètò nínú àwùjo̩ rè̩ àti ní gbogbo àwùjo̩ àgbáyé níbi tí àwo̩n è̩tó̩ òmìnira tí a ti gbé ka…
143 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní àwo̩n ojús̩e kan sí àwùjo̩, nípasè̩ èyí tí ó fi lè s̩eé s̩e fún e̩ni náà lát…
145e̩nì kò̩ò̩kan láti fi ò̩wò̩ àti ìmo̩yì tí ó tó̩ fún è̩tó̩ àti òmìnira àwo̩n e̩lòmíràn nígbà tí e̩n…
147 3. A kò gbo̩dò̩ lo àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí rárá, ní ò̩nà yòówù kó jé̩, tó bá lòdì sí àwo̩n è…
150 …n tí ó fún orílè̩‐èdè kan tàbí àkójo̩pò̩ àwo̩n ènìyàn kan tàbí e̩nìké̩ni ní è̩tó̩ láti s̩e ohunkóh…