Lines Matching refs:ti

5 Bí ó ti jé̩ pé s̩ís̩e àkíyèsí iyì tó jé̩ àbímó̩ fún è̩dá àti ìdó̩gba è̩tó̩ t̩í kò s̩eé mú kúrò tí è̩dá kò̩ò̩kan ní, ni òkúta ìpìlè̩ fún òmìnira, ìdájó̩ òdodo àti àlàáfíà lágbàáyé,
7 Bí ó ti jé̩ pé àìka àwo̩n è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn sí àti ìké̩gàn àwo̩n è̩tó̩ wò̩nyí ti s̩e okùnfà fún àwo̩n ìwà búburú kan, tó mú è̩rí‐o̩kàn è̩dá gbo̩gbé̩, tó sì jé̩ pé ìbè̩rè̩ ìgbé ayé titun, nínú èyí tí àwo̩n ènìyàn yóò ti ní òmìnira òrò̩ síso̩ àti òmìnira láti gba ohun tó bá wù wó̩n gbó̩, òmìnira ló̩wó̩ è̩rù àti òmìnira ló̩wó̩ àìní, ni a ti kà sí àníyàn tó ga jù lo̩ ló̩kàn àwo̩n o̩mo̩‐èniyàn,
9 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí a dáàbò bo àwo̩n è̩tó o̩mo̩nìyàn lábé̩ òfin, bí a kò bá fé̩ ti àwo̩n ènìyàn láti ko̩jú ìjà sí ìjo̩ba ipá àti ti amúnisìn, nígbà tí kò bá sí ò̩nà àbáyo̩ mìíràn fún wo̩n láti bèèrè è̩tó̩ wo̩n,
11 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí ìdàgbàsókè ìbás̩epò̩ ti ò̩ré̩‐sí‐ò̩ré̩ wà láàrin àwo̩n orílè̩‐èdè,
13 Bí ó ti jé̩ pé gbogbo o̩mo̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé tún ti te̩nu mó̩ ìpinnu tí wó̩n ti s̩e té̩lè̩ nínú ìwé àdéhùn wo̩n, pé àwo̩n ní ìgbàgbó̩ nínú è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí, ìgbàgbó̩ nínú iyì àti è̩ye̩ è̩dá ènìyàn, àti ìgbàgbó̩ nínú ìdó̩gba è̩tó̩ láàrin o̩kùnrin àti obìnrin, tó sì jé̩ pé wó̩n tún ti pinnu láti s̩e ìgbéláruge̩ ìtè̩síwájú àwùjo̩ nínú èyí tí òmìnira ètò ìgbé‐ayé rere è̩dá ti lè gbòòrò sí i,
15 Bí ó ti jé̩ pé àwo̩n o̩mo̩ e̩gbé̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé ti jé̩jè̩é̩ láti fo̩wó̩s̩owó̩ pò̩ pè̩lú Àjo̩ náà, kí won lè jo̩ s̩e às̩eyege nípa àmús̩e̩ àwo̩n è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn àti òmìnira è̩dá tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí àti láti rí i pé à ń bò̩wò̩ fún àwo̩n è̩tó̩ náà káríayé,
17 Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩ yìí ní kíkún,
21 Àpapò̩ ìgbìmò̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé s̩e ìkéde káríayé ti è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn, gé̩gé̩ bí ohun àfojúsùn tí gbogbo è̩dá àti orílè̩‐èdè jo̩ ń lépa ló̩nà tó jé̩ pé e̩nì kò̩ò̩kan àti è̩ka kò̩ò̩kan láwùjo̩ yóò fi ìkéde yìí só̩kàn, tí wo̩n yóò sì rí i pé àwo̩n lo ètò‐ìkó̩ni àti ètò‐è̩kó̩ láti s̩e ìgbéláruge̩ ìbò̩wò̩ fún è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí. Bákan náà, a gbo̩dò̩ rí àwo̩n ìgbésè̩ tí ó lè mú ìlo̩síwájú bá orílè̩‐èdè kan s̩os̩o tàbí àwo̩n orílè̩‐èdè sí ara wo̩n, kí a sì rí i pé a fi ò̩wò̩ tó jo̩jú wo̩ àwo̩n òfin wò̩nyí, kí àmúlò wo̩n sì jé̩ káríayé láàrin àwo̩n ènìyàn orílè̩‐èdè tó jé̩ o̩mo̩ Àjo̩‐ìsò̩kan àgbáyé fúnra wo̩n àti láàrin àwo̩n ènìyàn orílè̩‐èdè mìíràn tó wà lábé̩ às̩e̩ wo̩n.
24 Gbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira; iyì àti è̩tó̩ kò̩ò̩kan sì dó̩gba. Wó̩n ní è̩bùn ti làákàyè àti ti è̩rí‐o̩kàn, ó sì ye̩ kí wo̩n ó máa hùwà sí ara wo̩n gé̩gé̩ bí o̩mo̩ ìyá.
27 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní ànfàní sí gbogbo è̩tó̩ àti òmìnira tí a ti gbé kalè̩ nínú ìkéde yìí láìfi ti ò̩rò̩ ìyàtò̩ è̩yà kankan s̩e; ìyàtò̩ bí i ti è̩yà ènìyàn, àwò̩, ako̩‐n̄‐bábo, èdè, è̩sìn, ètò ìs̩èlú tàbí ìyàtò̩ nípa èrò e̩ni, orílè̩‐èdè e̩ni, orírun e̩ni, ohun ìní e̩ni, ìbí e̩ni tàbí ìyàtò̩ mìíràn yòówù kó jé̩. Síwájú sí i, a kò gbo̩dò̩ ya e̩nìké̩ni só̩tò̩ nítorí irú ìjo̩ba orílè̩‐èdè rè̩ ní àwùjo̩ àwo̩n orílè̩‐èdè tàbí nítorí ètò‐ìs̩èlú tàbí ètò‐ìdájó̩ orílè̩‐èdè rè̩; orílè̩‐èdè náà ìbáà wà ní òmìnira tàbí kí ó wà lábé̩ ìs̩àkóso ilè̩ mìíràn, wo̩n ìbáà má dàá ìjo̩ba ara wo̩n s̩e tàbí kí wó̩n wà lábé̩ ìkáni‐lápá‐kò yòówù tí ìbáà fé̩ dí òmìnira wo̩n ló̩wó̩ gé̩gé̩ bí orílè̩‐èdè.
43 Gbogbo ènìyàn ló dó̩gba lábé̩ òfin. Wó̩n sì ní è̩tó̩ sí àà bò lábé̩ òfin láìsí ìyàsó̩tò̩ kankan. Gbogbo ènìyàn ló ní è̩tó̩ sí ààbò tó dó̩gba kúrò ló̩wó̩ ìyàsó̩tò̩ yòówù tí ìbáà lòdì sí ìkéde yìí àti è̩tó̩ kúrò ló̩wó̩ gbogbo ohun tó bá lè ti ènìyàn láti s̩e irú ìyàsó̩tò̩ bé̩è̩.
55 1. E̩nìké̩ni tí a fi è̩sùn kàn ni a gbo̩dò̩ gbà wí pé ó jàrè títí è̩bi rè̩ yóò fi hàn lábé̩ òfin nípasè̩ ìdájó̩ tí a s̩e ní gban̄gba nínú èyí tí e̩ni tí a fi è̩sùn kàn yóò ti ní gbogbo ohun tí ó nílò láti fi s̩e àwíjàre ara rè̩.
78 1. To̩kùnrin tobìnrin tó bá ti bàlágà ló ní è̩tó̩ láti fé̩ ara wo̩n, kí wó̩n sì dá e̩bí ti wo̩n sílè̩ láìsí ìkanilápá‐kò kankan nípa è̩yà wo̩n, tàbí orílè̩‐èdè wo̩n tàbí è̩sìn wo̩n. E̩tó̩ wo̩n dó̩gba nínú ìgbeyàwó ìbáà jé̩ nígbà tí wo̩n wà papò̩ tàbí lé̩yìn tí wó̩n bá ko̩ ara wo̩n.
90 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmìnira èrò, òmìnira è̩rí‐o̩kàn àti òmìnira e̩ sìn. E̩tó̩ yìí sì gbani láàyè láti pààrò̩ e̩ sìn tàbí ìgbàgbó̩ e̩ni. Ó sì fún e̩yo̩ e̩nì kan tàbí àkójo̩pò̩ ènìyàn láàyè láti s̩e è̩sìn wo̩n àti ìgbàgbó̩ wo̩n bó s̩e je̩ mó̩ ti ìkó̩ni, ìs̩esí, ìjó̩sìn àti ìmús̩e ohun tí wó̩n gbàgbó̩ yálà ní ìkò̩kò̩ tàbí ní gban̄gba.
128 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kó̩ è̩kó̩. Ó kéré tán, è̩kó̩ gbo̩dò̩ jé̩ ò̩fé̩ ní àwo̩n ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩. E̩kó̩ ní ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩ yìí sì gbo̩dò̩ jé̩ dandan. A gbo̩dò̩ pèsè è̩kó̩ is̩é̩‐o̩wó̩, àti ti ìmò̩‐è̩ro̩ fún àwo̩n ènìyàn lápapò̩. Àn fàní tó dó̩gba ní ilé‐è̩kó̩ gíga gbo̩dò̩ wà ní àró̩wó̩tó gbogbo e̩ni tó bá tó̩ sí.
135 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láìjé̩ pé a fi ipá mú un láti kópa nínú àpapò̩ ìgbé ayé àwùjo̩ rè̩, kí ó je̩ ìgbádùn gbogbo ohun àmús̩e̩ wà ibè̩, kí ó sì kópa nínú ìdàgbàsókè ìmò̩ sáyé̩n sì àti àwo̩n àn fàní tó ń ti ibè̩ jáde.
140 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ètò nínú àwùjo̩ rè̩ àti ní gbogbo àwùjo̩ àgbáyé níbi tí àwo̩n è̩tó̩ òmìnira tí a ti gbé kalè̩ nínú ìkéde yìí yóò ti jé̩ mímús̩e̩.