Lines Matching +refs:E +refs:e

5 Bí ó ti jé̩ pé s̩ís̩e àkíyèsí iyì tó jé̩ àbímó̩ fún è̩dá àti ìdó̩gba è̩tó̩ t̩í kò s̩eé mú kúrò tí è…
7 Bí ó ti jé̩ pé àìka àwo̩n è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn sí àti ìké̩gàn àwo̩n è̩tó̩ wò̩nyí ti s̩e okùnfà fún àwo̩…
9 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí a dáàbò bo àwo̩n è̩tó o̩mo̩nìyàn lábé̩ òfin, bí a kò bá fé̩ ti àwo̩n…
11 Bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí ìdàgbàsókè ìbás̩epò̩ ti ò̩ré̩‐sí‐ò̩ré̩ wà láàrin àwo̩n orílè̩‐èdè,
13e té̩lè̩ nínú ìwé àdéhùn wo̩n, pé àwo̩n ní ìgbàgbó̩ nínú è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí, ì…
15e̩gbé̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé ti jé̩jè̩é̩ láti fo̩wó̩s̩owó̩ pò̩ pè̩lú Àjo̩ náà, kí won lè …
17 Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩…
21e ìkéde káríayé ti è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn, gé̩gé̩ bí ohun àfojúsùn tí gbogbo è̩dá àti orílè̩‐èdè jo̩ ń l…
27 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní ànfàní sí gbogbo è̩tó̩ àti òmìnira tí a ti gbé kalè̩ nínú ìkéde yìí láìfi ti ò̩…
31 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti wà láàyè, è̩tó̩ sí òmìnira àti è̩tó̩ sí ààbò ara rè̩.
34 A kò gbo̩dò̩ mú e̩niké̩ni ní e̩rú tàbí kí a mú un sìn; e̩rú níní àti ò wò e̩rú ni a gbo̩dò̩ fi òfin…
37 A kò gbo̩dò̩ dá e̩nì ké̩ni lóró tàbí kí a lò ó ní ìlò ìkà tí kò ye̩ o̩mo̩ ènìyàn tàbí ìlò tó lè tàb…
40 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ pé kí a kà á sí gé̩gé̩ bí ènìyàn lábé̩ òfin ní ibi gbogbo.
43 …òdì sí ìkéde yìí àti è̩tó̩ kúrò ló̩wó̩ gbogbo ohun tó bá lè ti ènìyàn láti s̩e irú ìyàsó̩tò̩ bé̩è̩.
46 E̩nì kò̩ò̩kan lórílè̩‐èdè, ló ní è̩tó̩ sí àtúns̩e tó jo̩jú ní ilé‐e̩jó̩ fún ìwà tó lòdì sí è̩tó̩ o̩…
52 E̩nì kò̩ò̩kan tí a bá fi è̩sùn kàn ló ní è̩tó̩ tó dó̩gba, tó sì kún, láti s̩àlàyé ara rè̩ ní gban̄g…
55E̩nìké̩ni tí a fi è̩sùn kàn ni a gbo̩dò̩ gbà wí pé ó jàrè títí è̩bi rè̩ yóò fi hàn lábé̩ òfin nípa…
57e̩nìké̩ni fún pé ó hu ìwà kan tàbí pé ó s̩e àwo̩n àfojúfò kàn nígbà tó jé̩ pé lásìkò tí èyí s̩e̩lè…
60 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ pé kí a má s̩àdédé s̩e àyo̩júràn sí ò̩rò̩ ìgbésí ayé rè̩, tàbí sí ò̩rò̩e̩…
63 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti rìn káàkiri ní òmìnira kí ó sì fi ibi tó bá wù ú s̩e ìbùgbé láàri…
65 2. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kúrò lórílè̩‐èdè yòówù kó jé̩, tó fi mó̩ orílè̩‐èdè tirè̩, kí ó s…
68 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti wá ààbò àti láti je̩ àn fàní ààbò yìí ní orílè̩‐èdè mìíràn nígbà …
70 …. A kò lè lo è̩tó̩ yìí fún e̩ni tí a bá pè lé̩jó̩ tó dájú nítorí e̩ s̩è̩ tí kò je̩ mó̩ ò̩rò̩ ìs̩èl…
73 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti jé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè kan.
75 …. A kò lè s̩àdédé gba è̩tó̩ jíjé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè e̩ni ló̩wó̩ e̩nìké̩ni láìnídìí tàbí kí a kò̩ fú…
78 …̩ ara wo̩n, kí wó̩n sì dá e̩bí ti wo̩n sílè̩ láìsí ìkanilápá‐kò kankan nípa è̩yà wo̩n, tàbí orílè̩…
80 2. A kò gbo̩dò̩ s̩e ìgbeyàwó kan láìjé̩ pé àwo̩n tí ó fé̩ fé̩ ara wo̩n ní òmìnira àto̩kànwá tó péye…
82 3. E̩bí jé̩ ìpìlè̩ pàtàkì àdánidá ní àwùjo̩, ó sì ní è̩tó̩ pé kí àwùjo̩ àti orílè̩‐èdè ó dáàbò bò ó.
85 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti dá ohun ìní ara rè̩ ní tàbí láti ní in papò̩ pè̩lú àwo̩n mìíràn.
87 2. A kò lè s̩àdédé gba ohun ìní e̩nì kan ló̩wó̩ rè̩ láìnídìí.
90 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmìnira èrò, òmìnira è̩rí‐o̩kàn àti òmìnira e̩ sìn. E̩tó̩ yìí sì gbani…
93 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmì nira láti ní ìmò̩ràn tí ó wù ú, kí ó sì so̩ irú ìmò̩ràn bé̩è̩ jáde…
96 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmìnira láti pé jo̩ pò̩ àti láti dara pò̩ mó̩ àwo̩n mìíràn ní àlàáf…
98 2. A kò lè fi ipá mú e̩nìké̩ni dara pò̩ mó̩ e̩gbé̩ kankan.
101 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kópa nínú ìs̩àkóso orílè̩‐èdè rè̩, yálà fúnra rè̩ tàbí nípasè̩ àw…
103 2. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ tó dó̩gba láti s̩e is̩é̩ ìjo̩ba ní orílè̩‐èdè rè̩.
105 … jé̩ òkúta ìpìlè̩ fún à s̩e̩ ìjo̩ba; a ó máa fi ìfé̩ yìí hàn nípasè̩ ìbò tòótó̩ tí a ó máa dì láti…
108 E̩nì kò̩ò̩kan gé̩gé̩ bí è̩yà nínú àwùjo̩ ló ní è̩tó̩ sí ìdáàbò bò láti o̩wó̩ ìjo̩ba àti láti jé̩ àn…
111E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti s̩is̩é̩, láti yan irú is̩é̩ tí ó wù ú, lábé̩ àdéhùn tí ó tó̩ tí ó s…
113 2. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti gba iye owó tí ó dó̩gba fún irú is̩é̩ kan náà, láìsí ìyàsó̩tò̩ ka…
115 3. E̩nì kò̩ò̩kan tí ó bá ń s̩isé̩ ní è̩tó̩ láti gba owó os̩ù tí ó tó̩ tí yóò sì tó fún òun àti e̩bí…
117 4. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti dá e̩gbé̩ òs̩ìs̩é̩ sílè̩ àti láti dara pò̩ mó̩ irú e̩gbe̩; bé̩è̩ …
120 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ìsinmi àti fàájì pè̩lú àkókò tí kò pò̩ jù lé̩nu is̩é̩ àti àsìkò ìsinmi…
123E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti gbé ìgbé ayé tó bójú mu nínú èyí tí òun àti e̩bí rè̩ yóò wà ní ìler…
128E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kó̩ è̩kó̩. Ó kéré tán, è̩kó̩ gbo̩dò̩ jé̩ ò̩fé̩ ní àwo̩n ilé‐è̩kó̩ a…
130eé‐má‐nìí. E tò è̩kó̩ gbo̩dò̩ lè rí i pé è̩mí; ìgbó̩ra‐e̩ni‐yé, ìbágbépò̩ àlàáfíà, àti ìfé̩ ò̩ré̩‐…
135 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láìjé̩ pé a fi ipá mú un láti kópa nínú àpapò̩ ìgbé ayé àwùjo̩ rè̩, kí…
137 2. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ààbò àn fàní ìmo̩yì àti ohun ìní tí ó je̩ yo̩ láti inú is̩é̩ yòówù …
140 E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ètò nínú àwùjo̩ rè̩ àti ní gbogbo àwùjo̩ àgbáyé níbi tí àwo̩n è̩tó̩ òm…
143 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní àwo̩n ojús̩e kan sí àwùjo̩, nípasè̩ èyí tí ó fi lè s̩eé s̩e fún e̩ni náà lát…
145 …de e̩nì kò̩ò̩kan láti fi ò̩wò̩ àti ìmo̩yì tí ó tó̩ fún è̩tó̩ àti òmìnira àwo̩n e̩lòmíràn nígbà tí
150 …n tí ó fún orílè̩‐èdè kan tàbí àkójo̩pò̩ àwo̩n ènìyàn kan tàbí e̩nìké̩ni ní è̩tó̩ láti s̩e ohunkóh…