Lines Matching refs:A

34 A kò gbo̩dò̩ mú e̩niké̩ni ní e̩rú tàbí kí a mú un sìn; e̩rú níní àti ò wò e̩rú ni a gbo̩dò̩ fi òfin dè ní gbogbo ò̩nà.
37 A kò gbo̩dò̩ dá e̩nì ké̩ni lóró tàbí kí a lò ó ní ìlò ìkà tí kò ye̩ o̩mo̩ ènìyàn tàbí ìlò tó lè tàbùkù è̩dá ènìyàn.
49 A kò gbo̩dò̩ s̩àdédé fi òfin mú ènìyàn tàbí kí a kàn gbé ènìyàn tì mó̩lé, tàbí kí a lé ènìyàn jáde ní ìlú láìnídìí.
57 2. A kò gbo̩dò̩ dá è̩bi è̩s̩è̩ fún e̩nìké̩ni fún pé ó hu ìwà kan tàbí pé ó s̩e àwo̩n àfojúfò kàn nígbà tó jé̩ pé lásìkò tí èyí s̩e̩lè̩, irú ìwà bé̩è̩ tàbí irú àfojúfò bé̩è̩ kò lòdì sí òfin orílè̩‐èdè e̩ni náà tàbí òfin àwo̩n orílè̩‐èdè àgbáyé mìíràn. Bákan náà, ìje̩níyà tí a lè fún e̩ni tó dé̩s̩è̩ kò gbo̩dò̩ ju èyí tó wà ní ìmúlò ní àsìkò tí e̩ni náà dá è̩s̩è̩ rè̩.
70 2. A kò lè lo è̩tó̩ yìí fún e̩ni tí a bá pè lé̩jó̩ tó dájú nítorí e̩ s̩è̩ tí kò je̩ mó̩ ò̩rò̩ ìs̩èlú tàbí ohun mìíràn tí ó s̩e tí kò bá ète àti ìgbékalè̩ Ajo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé mu.
75 2. A kò lè s̩àdédé gba è̩tó̩ jíjé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè e̩ni ló̩wó̩ e̩nìké̩ni láìnídìí tàbí kí a kò̩ fún e̩nìké̩ni láti yàn láti jé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè mìíràn.
80 2. A kò gbo̩dò̩ s̩e ìgbeyàwó kan láìjé̩ pé àwo̩n tí ó fé̩ fé̩ ara wo̩n ní òmìnira àto̩kànwá tó péye láti yàn fúnra wo̩n.
87 2. A kò lè s̩àdédé gba ohun ìní e̩nì kan ló̩wó̩ rè̩ láìnídìí.
98 2. A kò lè fi ipá mú e̩nìké̩ni dara pò̩ mó̩ e̩gbé̩ kankan.
125 2. A ní láti pèsè ìtó̩jú àti ìrànló̩wó̩ pàtàkì fún àwo̩n abiyamo̩ àti àwo̩n o̩mo̩dé. Gbogbo àwo̩n o̩mo̩dé yóò máa je̩ àwo̩n àn fàní ààbò kan náà nínú àwùjo̩ yálà àwo̩n òbí wo̩n fé̩ ara wo̩n ni tàbí wo̩n kò fé̩ ara wo̩n.
128 1. E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kó̩ è̩kó̩. Ó kéré tán, è̩kó̩ gbo̩dò̩ jé̩ ò̩fé̩ ní àwo̩n ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩. E̩kó̩ ní ilé‐è̩kó̩ alákò̩ó̩bè̩rè̩ yìí sì gbo̩dò̩ jé̩ dandan. A gbo̩dò̩ pèsè è̩kó̩ is̩é̩‐o̩wó̩, àti ti ìmò̩‐è̩ro̩ fún àwo̩n ènìyàn lápapò̩. Àn fàní tó dó̩gba ní ilé‐è̩kó̩ gíga gbo̩dò̩ wà ní àró̩wó̩tó gbogbo e̩ni tó bá tó̩ sí.
147 3. A kò gbo̩dò̩ lo àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí rárá, ní ò̩nà yòówù kó jé̩, tó bá lòdì sí àwo̩n ète àti ìgbékalè̩ Ajo̩‐àpapò̩ orílè̩‐èdè agbáyé.
150 A kò gbo̩dò̩ túmò̩ ohunkóhun nínú ìkéde yìí gé̩gé̩ bí ohun tí ó fún orílè̩‐èdè kan tàbí àkójo̩pò̩ àwo̩n ènìyàn kan tàbí e̩nìké̩ni ní è̩tó̩ láti s̩e ohunkóhun tí yóò mú ìparun bá èyíkéyìí nínú àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira tí a kéde yìí.